GB’ ohun to t’ orun wa ti wi
First time here? Explore the hymn tools.
Verse 1
GB’ ohun to t’ orun wa ti wi,
Bukun f’ oku onigbagbo
Nwon bo ninu lala aiye
Aiye ki yio tun mo won mo,
Ma sokun mo, Ma sokun mo,
Onigbagbo ma sokun mo
Onigbagbo ma sokun mo
Verse 2
Ese t’ onigbagbo nsofo,
F’ awon to sun ninu Kristi,
Gbati inu enia baje
Awon Angeli nyo l’ oke,
Verse 3
Onigbagbo to ku l’ aye,
F’ ibanuje f’ awon ara,
Sugbon awon ogun orun
F’ ayo gbe e’ ese Jesu.
Verse 4
Jesu si f’ oju ayo wo,
Omo odo na l’ ese Re,
O si fi iyonu kip e;
O seun omo odor ere.
Verse 5
Onigbagbo ma jafara,
Ninu ajo re l’ aiye yi,
Ki ade ogo je tire,
Pelu irawo ti ki sa;
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.