ILE ewa wonni, b’ o ti dara to
First time here? Explore the hymn tools.
Verse 1
ILE ewa wonni, b’ o ti dara to!
Ibugbe Olorun, t’ oju ko ti ri;
Tal’ o fe ibe, lehin aiye yi?
Tal’ o fe k’ a wo on ni aso funfun?
Verse 2
Awon wonni, t’ o ji ninu orun won;
Awon t’ o n’ igbagbo si nkan t’ a ko ri;
Awon t’ o k’ aniyan won l’ Olugbala,
Awon ti ko tiju agbelebu Krist’.
Verse 3
won ti ko nani gbogbo nkan aiye,
Awon t’ o le s’ oto de oju iku,
Awon t’ o nrubo ife l’ ojojumo,
Awon t’ a f’ igbala Jesu ra pada.
Verse 4
Itiju ni fun nyin, Om’-ogun Jesu,
Enyin ara ilu ibugbe orun,
Kinla! E nfi fere at’ ilu sire,
‘Gbat’ O ni k’ e sise, t’ O sip e, “E ja?”
Verse 5
B’ igbi omi aiye si ti nkolu wa,
Jesu, Oba-Ogo, so si wa l’ eti
Adun t’o wa l’orun, ilu mimo ni
Nibit’ isimi wa lai ati lailai
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.