A! mba le l’ egberun ahon
A! mba le l’ egberun ahon. Fun ‘yin Olugbala, Ogo Olorun Oba mi, Isegun ore Re.
Read hymn : A! mba le l’ egberun ahonA! mba le l’ egberun ahon. Fun ‘yin Olugbala, Ogo Olorun Oba mi, Isegun ore Re.
Read hymn : A! mba le l’ egberun ahonA! NWON ti gun s’ ebute, L’ oke orun; L’ oke orun; Ebi ko ni pa won mo, Nwon bo lowo irora,
Read hymn : A! NWON ti gun s’ ebuteA! RO ti ibugbe orun, Li eba odo imole, Nibit’ awon mimo wa l’ aiku, T’ a wo won li aso funfun.
Read hymn : A! RO ti ibugbe orunA, JEKI oro mimo Re Fi agbara si okan mi, F’ imole at’ ife orun Wi f’ okan mi pe, “Wo t’ emi.”
Read hymn : A, JEKI oro mimo ReA, JESU Alabukun, A m’ orin ayo wa, Ohun at’ okan ‘pe wa L’ ayo l’ a gbe si O;
Read hymn : A, JESU AlabukunABA le n’ igbagbo aye, B’ o ti wu k’ ota po; Igbagbo ti ko je mira Fun aini at’ os
Read hymn : ABA le n’ igbagbo ayeA BAPTIS’ wa sinu iku, Nipa itebo ‘mi; A sin wa ‘nu ‘boji Jesu, A sin wa pelu Re.
Read hymn : A BAPTIS’ wa sinu iku“ABBA, Baba,” a sunmo O L’ oruko Jesu owon; Aw’ omo Re t’ o pe nihin, Nfe ‘bukun t’ O se ‘leri;
Read hymn : ABBA, Baba,” a sunmo OABE, a fe ri o, Ojo ‘simi rere, Gbogbo ose a ma wipe, Iwo o ti pe to?
Read hymn : ABE, a fe ri oADUA didun adua didun, T’o gbe mi lo kuro l’aiye, Lo ‘waju ite Baba mi, Ki nso gbogbo edun mi fun;
Read hymn : ADUA didun adua didunAFRIK’ ‘le wara at’ oyin, Ni orile aiye now si, T’ Olorun fun ania dudu, Fun ini re titi lailai.
Read hymn : AFRIK’ ‘le wara at’ oyinAFUN iho ayo mimu S’ Olorun Oba nla! K’ile gbogbo lo ahon won K’o si korin ‘segun.
Read hymn : AFUN iho ayo mimuA F’ iyin aiku fun ‘Fe Olorun Baba, Fun itunu t’ aiye, At’ ireti t’ orun:
Read hymn : A F’ iyin aiku funA F’ ope f’ Olorun L’ okan ati ohun wa, Eni s’ ohun ‘yanu, Ninu Enit’ araiye nyo;
Read hymn : A F’ ope f’ OlorunAGBELEBU ni ere mi, Nibe ni a rubo fun mi; Nibe l’ a kan Oluwa mo Nibe l’ Olugbala mi ku.
Read hymn : AGBELEBU ni ere miAGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi,
Read hymn : AGOGO ihinrereA IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa On o si dide fun igbala mi; Ki nsa ma gbagura, On o se ‘ranwo; ‘Gba Krist’ wa lodo mi, ifoiya ko si.
Read hymn : A IGBAGBO bila! T’ emi l’ OluwaAJAGUN Jesu l’ emi bi, At’ omo ehin Re? Ngo ha beru lati wasu Agbara isin Re?
Read hymn : AJAGUN Jesu l’ emi biA JESU, Iwo nduro Lode, lehin ‘lekun, Iwo fi suru duro Lati koja s’ ile;
Read hymn : A JESU, Iwo nduroAJIGBESE anu ni mi, Mo ti ba majemu mi je; Laifoya ninu pipe Re, Mo gb’ ara at ore mi wa.
Read hymn : AJIGBESE anu ni miA JIN jin, oru mimo, Okun su, mole de, Awon olus’ agutan nsona, Omo t’o wa l’ oju orun,
Read hymn : A JIN jin, oru mimoAKO ha gb’ oro wuwo ni, P’ a sin wa pelu Oluwa? P’ a te wa ri sinu ‘ku Re, A sib o ara osi ‘le.
Read hymn : AKO ha gb’ oro wuwo niAKOKO ati lo mi ya, Mo gb’ ohun to npe mi lo ‘le, Olorun jek’ iyonu pin, Jek’ iranse Re ku l’ ayo.
Read hymn : AKOKO ati lo mi yaAKOKO ‘re gbat’ eda te, Lati b’ Olorun re s’ oro, Lati f’ edun ranse s’ oke, Ati lati gb’ oro mimo.
Read hymn : AKOKO ‘re gbat’ eda te