IFE l’ Olorun: anu Re
IFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun.
Read hymn : IFE l’ Olorun: anu ReIFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun.
Read hymn : IFE l’ Olorun: anu ReIFE mi s’ ibi ti wa pe, Lai beru itiju, Titi mo fi r’ ohun titun, Ti o da mi duro.
Read hymn : IFE mi s’ ibi ti wa peIFE orun! alailegbe! N’nu ase mimo yi, Ogo re kun, ‘mole re po, Ti ntan iye jade.
Read hymn : IFE orun! alailegbeIfe orun, o ti dun to! Gbawo ni ngo ri t’okan mi, Y’o kun fun kiki re? Okan mi npongbe lati mo
Read hymn : Ife orun, o ti dun toIFE orun alailegbe, Ayo orun sokale: Fi okan wa se ‘bugbe Re, Se asetan anu Re;
Read hymn : IFE orun alailegbeIFE orun t’ o teriba Lati pin ninu ekun wa: Iwo l’ a k’ aniyan wa le, Ko si nkan gbat’ O sunmo wa.
Read hymn : IFE orun t’ o teribaIFE Re da wa si loni, L’ are a si dubule; Ma so wa n’ idake orun, K’ ota ma yow a l’enu:
Read hymn : IFE Re da wa si loniIFE t’ o rekoja ero, T’ o se ‘lana rere, Fun ‘gbala enia, ki Adam T’ o mu isubu wa.
Read hymn : IFE t’ o rekoja eroIGBAGBO l’ ategun t’ o so Orun at’ aiye po; On l’ Olugbala fi sise Iyanu Re l’ aiye.
Read hymn : IGBAGBO l’ ategun t’ o soIGBAGBO mi duro l’ori, Eje at’ododo Jesu; Nko je gbekele ohun kan, Lehin oruko nla Jesu;
Read hymn : IGBAGBO mi duro l’oriIGBAGBO mi nwo O, Iwo Od’-agutan, Olugbala Jo gbo adua mi,
Read hymn : IGBAGBO mi nwo OIGBALA ni, igbala ni, Awa elese nfe; Nitori ninu buburu, T’ a se l’ awa nsegbe.
Read hymn : IGBALA ni, igbala niIGBA wa mbe li owo Re, A fe ko wa nibe; A fie mi at’ ara wa Si abe iso Re.
Read hymn : IGBA wa mbe li owo ReIJA ti de, ipe sin dun kikankikan, “Wo ‘hamora!” nigbe jake-jado; Oluwa omo-ogun nlo si isegun, Ko pe ti segun Krist’ y’o farahan.
Read hymn : IJA ti de, ipe sin dun kikankikanIJINLE l’ oro Re, Jesu, Tani le tumo re? Tani gbon to! tani mo to! Tal’ oye re po to!
Read hymn : IJINLE l’ oro Re, JesuIKOSE ti po to, t’ a nri Li ona wa s’ ite anu Sibe, tani mo ‘yi adua Ti ki y’o fe ma wa nibe.
Read hymn : IKOSE ti po to, t’ a nriIKU l’ opin ohun gbogbo; B’ o ti wu k’ emi gun, Egun ni ko le sai ma se T’ a ti fi eda gun.
Read hymn : IKU l’ opin ohun gbogboILE-EKO ojo ‘sinmi, A, mo ti fe O to! Inu mi dun mo daraya Lati yo ayo re
Read hymn : ILE-EKO ojo ‘sinmiILE ayo kan wa Ti o Jina, Ti awon mimo wa; Nwon nran b’ orun;
Read hymn : ILE ayo kan waILE ewa wonni, b’ o ti dara to! Ibugbe Olorun, t’ oju ko ti ri; Tal’ o fe ibe, lehin aiye yi? Tal’ o fe k’ a wo on ni aso funfun?
Read hymn : ILE ewa wonni, b’ o ti dara toILE ‘simi, mo nreti re, ‘Gbawo n’ igba yio de, Ti ngo bo ‘hamora sile, Ti ngo wa pelu Krist”?
Read hymn : ILE ‘simi, mo nreti reILU mi, orin re, Ilu mi omnira Li emi nko; Il’ awon baba mi,
Read hymn : ILU mi, orin reILU t’ o dara po l’ aiye; Betlehem’, ‘wo ta won yo; Ninu re l’ Oluwa ti wa Lati j’ oba Israel’.
Read hymn : ILU t’ o dara po l’ aiyeIMOLE k’ okan mi loni, T’ o logo t’ o si ndan, T’ o tan ju t’ awosanma lo, Jesu n’ imole mi.
Read hymn : IMOLE k’ okan mi loni