MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni
MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni Isegun kan yio f’ ipa miran fun o Ma ja bi okunrin, segun ibinu Ma tejumo Jesu, yio mu o la ja
Read hymn : MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese niMA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni Isegun kan yio f’ ipa miran fun o Ma ja bi okunrin, segun ibinu Ma tejumo Jesu, yio mu o la ja
Read hymn : MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese niMA gesin lo l’ olanla Re; Gbo, gbogb’ aiye nke “Hosanna”, Olugbala ma lo pele Lori ‘m’ ope at aso.
Read hymn : MA gesin lo l’ olanla ReMA koja mi, Olugbala, Gbo adura mi; ‘Gbat’ Iwo ba np’ elomiran, Mase koja mi!
Read hymn : MA koja mi, OlugbalaMASE f’oiya ohun t’ o le de, Olorun y’o so o; Duro labe iye Re, Olorun y’o so o.
Read hymn : MASE f’oiya ohun t’ o le deMASE huwa ese, Ma soro ese; Omo Jesu l’ e se, Omo Oluwa.
Read hymn : MASE huwa eseMA sise lo, mase sare, Fi ayo sise Baba re; Bayi ni Jesu se l’ aiye Ko ha ye k’ awa ko se be?
Read hymn : MA sise lo, mase sareMA so fun mi l’ ohun aro Pe iye dabi ala; Okan ti ntogbe li o ku, ‘Kan ko ri bi a ti nro.
Read hymn : MA so fun mi l’ ohun aroMA so ra, okan mi, A won ota dide; Ogun ese si mura tan, Lati fa o lu ‘le.
Read hymn : MA so ra, okan miMA sun lo, olufe; sa ma simi, F’ ori re le aiya Olugbala; A fe o, sugbon Jesu fe o ju:- O di owuro o!
Read hymn : MA sun lo, olufe; sa ma simiMA toju, Jehofah nla, Ero l’ aiye osi yi, Emi ko l’ okun, iwo ni, F’ ow’ agbara di mi mu,
Read hymn : MA toju, Jehofah nlaMA wo ‘le, Jesu t’ a nreti, T’a bi lati gba ni la! Gba wa low’ ese at’ eru, K’ a r’ isimi ninu Re.
Read hymn : MA wo ‘le, Jesu t’ a nretiMIMO, mimo, mimo! Olodumare! Ni kutukutu n’Iwo o gbo orin wa; Mimo, mimo, mimo! Oniyonu julo! Ologo meta lai, Olubukun!
Read hymn : MIMO, mimo, mimo! Olodumare!mJE k’ agb’ oju ayo s’ oke Si agbala orun, K’ a yo lati ri Baba wa Lori ite ife.
Read hymn : mJE k’ agb’ oju ayo s’ okeMO duro de Olorun mi, O si gbo igbe mi, O ri mo simi l’ oro Re, O si mu ‘gbala wa.
Read hymn : MO duro de Olorun miMO fe gbo itan kanna T’ awon Angeli-nso; Bi Oba Ogo ti wa, Gbe aiye osi yi;
Read hymn : MO fe gbo itan kannaMO fe iyera s’ apakan Kuro l’ ero t’ aiye, Ki nf’ akoko iwo orun Kunle gba adura.
Read hymn : MO fe iyera s’ apakanMO fe ki ndabi Jesu, Ninu iwa pele; Ko s’ enit’ o gboro ‘binu L’ enu Re lekan ri.
Read hymn : MO fe ki ndabi JesuMO Fe mo nipa Jesu sii, F’or’ ofe Re h’ elomiran; Ki nle ri ‘gbala kikun Re, Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi.
Read hymn : MO Fe mo nipa Jesu siiMO fe O, Olorun, sugbon Ki se fun ere kan, Ki se nitori’ eniti Ko ba fe O yio ku,
Read hymn : MO fe O, Olorun, sugbonMO fe O n’gbagbogbo, Oluwa Olore Ko s’ ohun ti nfun ni L’ alafia bi Tire
Read hymn : MO fe O n’gbagbogbo,MO feran iwe oro Re; O f’ imole at’ ayo fun Okan okun on ‘banuje! Oro Re t’ oan mi wiwo;
Read hymn : MO feran iwe oro ReMO fi gbogbo re fun Jesu Patapata laiku kan; Ngo ma fe ngo si gbekele, Ngo si ma ba gbe titi.
Read hymn : MO fi gbogbo re fun JesuMO fi omije wo yika, Aiye su bi iji okun; Sibe, larin re, mo gb’ ohun, O nwi, je pe, “Wa sodo Mi!”
Read hymn : MO fi omije wo yikaMO f’ ara Mi fun o, Mo ku nitori re, Ki nle ra o pada, K’ o le jinde n’nu ‘ oku;
Read hymn : MO f’ ara Mi fun o