A F’ iyin aiku fun
A F’ iyin aiku fun ‘Fe Olorun Baba, Fun itunu t’ aiye, At’ ireti t’ orun:
Read hymn : A F’ iyin aiku funA F’ iyin aiku fun ‘Fe Olorun Baba, Fun itunu t’ aiye, At’ ireti t’ orun:
Read hymn : A F’ iyin aiku funA F’ ope f’ Olorun L’ okan ati ohun wa, Eni s’ ohun ‘yanu, Ninu Enit’ araiye nyo;
Read hymn : A F’ ope f’ OlorunAGBELEBU ni ere mi, Nibe ni a rubo fun mi; Nibe l’ a kan Oluwa mo Nibe l’ Olugbala mi ku.
Read hymn : AGBELEBU ni ere miAGOGO ihinrere Nlu lat’ ilu de ‘lu ‘Bukun ati ‘gbala ofe, Ni nwon fun o at’ emi,
Read hymn : AGOGO ihinrereA IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa On o si dide fun igbala mi; Ki nsa ma gbagura, On o se ‘ranwo; ‘Gba Krist’ wa lodo mi, ifoiya ko si.
Read hymn : A IGBAGBO bila! T’ emi l’ OluwaAJAGUN Jesu l’ emi bi, At’ omo ehin Re? Ngo ha beru lati wasu Agbara isin Re?
Read hymn : AJAGUN Jesu l’ emi biA JESU, Iwo nduro Lode, lehin ‘lekun, Iwo fi suru duro Lati koja s’ ile;
Read hymn : A JESU, Iwo nduroAJIGBESE anu ni mi, Mo ti ba majemu mi je; Laifoya ninu pipe Re, Mo gb’ ara at ore mi wa.
Read hymn : AJIGBESE anu ni miA JIN jin, oru mimo, Okun su, mole de, Awon olus’ agutan nsona, Omo t’o wa l’ oju orun,
Read hymn : A JIN jin, oru mimoAKO ha gb’ oro wuwo ni, P’ a sin wa pelu Oluwa? P’ a te wa ri sinu ‘ku Re, A sib o ara osi ‘le.
Read hymn : AKO ha gb’ oro wuwo niAKOKO ati lo mi ya, Mo gb’ ohun to npe mi lo ‘le, Olorun jek’ iyonu pin, Jek’ iranse Re ku l’ ayo.
Read hymn : AKOKO ati lo mi yaAKOKO ‘re gbat’ eda te, Lati b’ Olorun re s’ oro, Lati f’ edun ranse s’ oke, Ati lati gb’ oro mimo.
Read hymn : AKOKO ‘re gbat’ eda te