SIMI le Oluwa -e gbo
SIMI le Oluwa -e gbo Orin duru orun – Simi le ife ailopin, Si duro je,
Read hymn : SIMI le Oluwa -e gboSIMI le Oluwa -e gbo Orin duru orun – Simi le ife ailopin, Si duro je,
Read hymn : SIMI le Oluwa -e gboSION yara, k’ o je ise giga re, So f’ aiye pe Olorun ni mole, Eni to da ‘won orilede ko fe, K’ enikan segbe s’ inu okunkun.
Read hymn : SION yara, k’ o je ise giga reSI pepe Oluwa, Mo mu ‘banuje wa; ‘Wo ki f’ anu tewogba Ohun alaiye yi?
Read hymn : SI pepe OluwaSISE, akoko nlo, Se tokantokan; Sise, okan nsegbe, Sise, oru mbo,
Read hymn : SISE, akoko nloSISE tori oru mbo ! Sise li owuro; Sise nigba iri nse, sise n’nu ‘tanna; Sise ki osan to pon, sise nigb’ orun nran, Sise tori oru mbo ! ‘gb ise o pari.
Read hymn : SISE tori oru mbo ! Sise li owuroSO itan kanna fun mi, T’ ohun ni t’ a ko ri; Ti Jesu on ogo Re, Ti Jesu En ‘ ife,
Read hymn : SO itan kanna fun miSUNM’ odo wa, Emmanuel, Wa’ra Israel pada, T’ on sofo li oko eru Titi Jesu y’o tun pada.
Read hymn : SUNM’ odo wa, EmmanuelTAL’ awon wonyi b’ iranwo, Niwaju ‘te Olorun? Gbogbo nwon de ade wura, Egbe ogo wo l’ eyi?
Read hymn : TAL’ awon wonyi b’ iranwo,TAL’ o mo adun isimi, B’ o ye l’ awon t’ o ni, Ti se ‘pin awon ayanfe, Nipa eje Jesu?
Read hymn : TAL’ o mo adun isimiTANI yio gbe Jabob’ dide?” Ore Jakob’ kop o; Eyi t’ o je ‘yanu nip e, Imo won ko s’ okan.
Read hymn : TANI yio gbe Jabob’ dideTIRE lailai l’ awa se, Baba Olorun ife; Je k’ a je Tire titi, L’ aiye yi, ati lailai.
Read hymn : TIRE lailai l’ awa seTIRE l’ awa Kristi, Titi aiyeraiye, A fe fi gbogbo okan wa Fun O patapata.
Read hymn : TIRE l’ awa KristiTIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re, O nso ife Re si mi: Sugbon mo fen de l’ apa igbagbo, Ki nle tubo sunmo O.
Read hymn : TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun ReTIRE l’ ola Baba, O wa n’ ikawo Re; B’ ojum’ ola si mo ba ni, Nipa ase Re ni.
Read hymn : TIRE l’ ola BabaTO nwon, Baba si O, To nwon si O; Awon omo wonyi Ti O fun ni,
Read hymn : TO nwon, Baba si OTORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo;
Read hymn : TORI Mi at’ ihinrereT’ IFE Jesu t’o wa mi, Gbat’ mo nu n’ ese; T’ ore ofe t’ o mu mi Pada bo sin’ agbo;
Read hymn : T’ IFE Jesu t’o wa miT’ OLORUN n’ ijoba gbogbo Oril-ede, e korin ‘yin: E so t’ ipa Re to tobi; Ola Re y’o m’ orin yin dun.
Read hymn : T’ OLORUN n’ ijoba gbogboWA, Emi ‘re, ‘Dada orun Pelu itunu lat’ oke; S’ alabo at’ Oluto wa, To ero at’ isise wa.
Read hymn : WA, Emi ‘re, ‘Dada orunWA, enyin olope, wa, Gbe orin ikore ga; Ire gbogbo ti wole K’ otutu oye to de;
Read hymn : WA, enyin olope, waWA, iwo isun ibukun, Je ki nkorin ore Re: Odo anu ti nsan titi, Bere orin ‘yin kikan;
Read hymn : WA, iwo isun ibukunWA, jek’ a tun pilese ajo wa, K’ a b’ odun yipo, K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de.
Read hymn : WA, jek’ a tun pilese ajo waWA, Jesu fi ara han; Wa, je k’okan wa mo O: Wa, mu gbogb’ okan gbona, Wa, bukun wa k’a to lo.
Read hymn : WA, Jesu fi ara hanWA, ma sise, Tani gbodo s’ole ninu oko, Gbati gbogbo enia nkore jo? Kaluku ni Baba pase fun pe, –
Read hymn : WA, ma sise