WO ‘le, ‘wo alabukunfun
WO ‘le, ‘wo alabukunfun; Wa l’ oruko Jesu owon; A f’ ohun kan ke, “Ma wole,” A ro pe Jesu kio pelu.
Read hymn : WO ‘le, ‘wo alabukunfunWO ‘le, ‘wo alabukunfun; Wa l’ oruko Jesu owon; A f’ ohun kan ke, “Ma wole,” A ro pe Jesu kio pelu.
Read hymn : WO ‘le, ‘wo alabukunfunWO ‘le ‘wo enit’ a bukun, O ki tun s’ alajo; A fi gbogbo okan gba o, ‘Wo arakunrin wa.
Read hymn : WO ‘le ‘wo enit’ a bukunYIKA or’ ite Olorun, Egberun ewe wa; Ewe t’ a dari ese ji, Awon egbe mimo,
Read hymn : YIKA or’ ite OlorunYIN Olorun Abra’am, T’ o gunwa lok’ orun, Eni agba aiyeraiye, Olorun ife;
Read hymn : YIN Olorun Abra’amYIN Olorun Oba wa, E ko orin ogo si, ‘Tor’ anu Re wa sibe, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : YIN Olorun Oba waYIN Olorun Oba wa; E gbe ohun iyin ga; Anu Re o wa titi, L’ ododo dajudaju.
Read hymn : YIN Olorun Oba waYin, enyin iji t’ o dide N’ igboran s’ ase Re K’ oke at’ igi eleso Dapo yin Oluwa.
Read hymn : YIN Oluwa, oro didunYIN Oluwa, orun wole Yin enyin mimo l’ oke K’ orun at’ osupa ko, K’ awon ‘rawo f’ iyin fun.
Read hymn : YIN Oluwa, orun woleYIN ‘Luwa, okan mi; Ki gbogbo inu mi, Ba mi yin oruko Eni T’ ife Re po julo.
Read hymn : YIN ‘Luwa, okan miYO, eyin onigbagbo, Je k’ imole nyin tan; Igba ale mbo tete, Oru si fere de.
Read hymn : YO, eyin onigbagboYO awon ti nsegbe, sajo eni nku, F’ anu ja won kuro ninu ese, Ke f’ awon ti nsina, gb’ eni subu ro, So fun won pe, Jesu le gba won la,
Read hymn : YO awon ti nsegbe, sajo eni nku