OKAN mi pe ninu Jesu
OKAN mi pe ninu Jesu: Ko beru ise ofin mo; Erin Olorun dun ninu, Nibit’ o ti kun f’ ese ri.
Read hymn : OKAN mi pe ninu JesuOKAN mi pe ninu Jesu: Ko beru ise ofin mo; Erin Olorun dun ninu, Nibit’ o ti kun f’ ese ri.
Read hymn : OKAN mi pe ninu JesuGBOGBO eje eran, Ti pepe awon ju, Ko le f’ okan l’ Alafia, Ko le we eri nu.
Read hymn : GBOGBO eje eran“ABBA, Baba,” a sunmo O L’ oruko Jesu owon; Aw’ omo Re t’ o pe nihin, Nfe ‘bukun t’ O se ‘leri;
Read hymn : ABBA, Baba,” a sunmo ONIWAJU ite anu Re, Jesu, a tun ko ‘ra wa de, A wa toro idariji, Fun majemu t’ a ti baje.
Read hymn : NIWAJU ite anu ReJESU a de l’ ojo oni Lati se ase Re, Jo masai wa si arin wa, K’ O f’ ola Re ran wa.
Read hymn : JESU a de l’ ojo oniO FUN mi l’ edidi, ‘Gbese nla ti mo je; B’ O ti fun mi, O si rerin Pe, “Mase gbegbe Mi!”
Read hymn : O FUN mi l’ edidiKIL’ o le w’ ese mi nu? Ko si, lehin eje Jesu; Kil’ o tun le wo mi san? Ko si, lehin eje Jesu.
Read hymn : KIL’ o le w’ ese mi nuPELU iwa mimo, b’ Oluwa s’ oro Be ‘nu Re n’ gbagbogbo je onje iye, B’ onigbagbo s’ ore, Ran ailera lowo; Ma gbagbe nigbakan, wa ibukun Re.
Read hymn : PELU iwa mimo, b’ Oluwa s’ oroALABUKUN n’ isun eje, T’ a fi han elese aiye; Olubukun n’ om Olorun, Nipa ‘na Re la wow a san,
Read hymn : ALABUKUN n’ isun eje“LO wasu Mi,” l’ Oluwa wi: Wi f’ aiye k’ o gba ore Mi; Enit’ o gb’ oro Mi y’o la, En’ti ko gbagbo y’o segbe.
Read hymn : LO wasu Mi,” l’ Oluwa wiOLUWA wa mimo, Ti ogun orun nyin, Masai gbo wa; Kerubu, Serafu,
Read hymn : OLUWA wa mimoJEK’ alore Sion dide Gba ipe fun ‘ra won; Jeki nwon gba ase wuwo Lat’ enu Oluwa.
Read hymn : JEK’ alore Sion dide