MO fi omije wo yika
MO fi omije wo yika, Aiye su bi iji okun; Sibe, larin re, mo gb’ ohun, O nwi, je pe, “Wa sodo Mi!”
Read hymn : MO fi omije wo yika643 hymns
MO fi omije wo yika, Aiye su bi iji okun; Sibe, larin re, mo gb’ ohun, O nwi, je pe, “Wa sodo Mi!”
Read hymn : MO fi omije wo yikaMO f’ ara Mi fun o, Mo ku nitori re, Ki nle ra o pada, K’ o le jinde n’nu ‘ oku;
Read hymn : MO f’ ara Mi fun oMO gbeke mi le O, Lori ibusun mi, Gba mi lowo irora mi, Ki O si wo mi san.
Read hymn : MO gbeke mi le OMO gbohun Jesu t’ o wipe, “Wa simi lodo Mi; Gbe ori re, ‘wo alare, Le okan aiya Mi.”
Read hymn : MO gbohun Jesu t’ o wipeMO ha le tun duro Laif’ ini mi toro? Ki nmu okan kuro l’ aiye, Ki ngba Olugbala?
Read hymn : MO ha le tun duroMO j’ alejo nihin, ‘nu ile ajeji, Ile mi jin rere, l’or’ ebute wura; Lati je iranse n’koja okun l’ohun, Mo nsise nihin f’ oba mi
Read hymn : MO j’ alejo nihin, ‘nu ile ajejiMO korin ipa Olorun, T’ O gbe oke dide, T’ O tan odo tin san kiri, T’ O si k’ orun giga.
Read hymn : MO korin ipa OlorunMO k’ ese mi le Jesu, Od’ agutan mimo; O ru gbogbo eru mi, O so mi d’ominira;
Read hymn : MO k’ ese mi le Jesu“MO mo p’Oludande mi mbe;” Itunu nla l’eyi fun mi! O mbe, Enit’ o ku lekan; O mbe, Ori iye mi lai.
Read hymn : MO mo p’Oludande mi mbeMO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogo, On na ko ko ni bi ore aiye sa; Tifetife li on nse ajo lori mi, Mo fe k’ Olugbala mi si je tire.
Read hymn : MO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogoMO n’ ‘ore, kan, A, Ore na! N’ ife mi k’ emi to mo, On f’ okun ife Re nla, Fa mi sunmo odo Re,
Read hymn : MO n’ ‘ore, kan, A, Ore naMO ti mb’ese rin ti pe, Pin wa n’iya, Oluwa, Ore’parun ni tire, Gba mi Jesu, mo segbe.
Read hymn : MO ti mb’ese rin ti pe