AKO n’ ibugbe kan nihin
AKO n’ ibugbe kan nihin, Eyi ba elese n’nu je; Ko ye k’ enia mimo kanu, ‘Tori nwon nfe ‘simi t’ orun.
Read hymn : AKO n’ ibugbe kan nihinAKO n’ ibugbe kan nihin, Eyi ba elese n’nu je; Ko ye k’ enia mimo kanu, ‘Tori nwon nfe ‘simi t’ orun.
Read hymn : AKO n’ ibugbe kan nihinAWON mimo! Ija nwon pin, Nwon segun aiye nikehin, Nwon ko fe ohun ija mo; Nwon da won si ese Jesu;
Read hymn : AWON mimo! Ija nwon pinTAL’ awon wonyi b’ iranwo, Niwaju ‘te Olorun? Gbogbo nwon de ade wura, Egbe ogo wo l’ eyi?
Read hymn : TAL’ awon wonyi b’ iranwo,EGBEGBERUN aimoye Nwon wo aso ala, Ogun awon t’a rapada Nwon kun ‘bi ‘mole naa;
Read hymn : EGBEGBERUN aimoyeOPO ikan omi, Yanrin kekeke; Wonyi l’ o d’ okun nla At’ ile aiye.
Read hymn : OPO ikan omiMASE huwa ese, Ma soro ese; Omo Jesu l’ e se, Omo Oluwa.
Read hymn : MASE huwa eseGBATI Samueli ji To ‘igb’ ohun Eleda Ni gbolohun kokan, Ayo re ti po to
Read hymn : GBATI Samueli jiOJ’ oni lo Jesu Baba, Boju Re w’ emi omo Re.
Read hymn : OJ’ oni loJESU Onirele, Omo Olorun: Alanu, Olufe, Gbo ‘gbe omode.
Read hymn : JESU OnireleGB’ adura wa Oluwa, F’ awon omo t’ O fun wa, Pin wa ninu ‘bukun Re, Si fun won l’ ayo l’ orun.
Read hymn : GB’ adura wa OluwaOLORUN Bethel, Eniti O mbo awon Tire; Enit’ o mu baba wa la Ojo aiye won ja.
Read hymn : OLORUN Bethel, EnitiJESU pe omode, O gbe won s’ aiya Re; O f’ owo Re gba won mora, O si sure fun won.
Read hymn : JESU pe omode