1. A JIN jin, oru mimo,
Okun su, mole de,
Awon olus’ agutan nsona,
Omo t’o wa l’ oju orun,
Simi n’nu alafia
Simi n’nu Alafia.
2. Ajin jin, oru mimo
Mole, de okun sa,
Oluso agutan gb’ orin Angeli,
Kabiyesi aliluya Oba,
Jesu olugbala de
Jesu olugbala de.
3. Ajin jin, oru mimo,
‘Rawo orun tan mole,
Wo awon Amoye ila orun,
Mu ore won wa fun Oba wa,
Jesu olugbala de
Jesu olugbala de
4. Ajin jin, oru mimo,
‘Rawo orun tan mole,
Ka pelu awon Angel korin,
Kabiyesi aliluya Oba
Jesu olugbala de
Jesu olugbala de.
(Visited 846 times, 1 visits today)