YBH 103

SUNM’ odo wa, Emmanuel

1. SUNM’ odo wa, Emmanuel,
Wa’ra Israel pada,
T’ on sofo li oko eru
Titi Jesu y’o tun pada.
E yo, e yo, Emmanuel
Y’ o wa s’ odo wa Israel.

2. Wa, Opa alade Jesse,
K’ o gba wa l’ owo ota wa
Gba wa low orun apadi
Fun wa n’ isegun l’ ori ‘ku,

3. Sunmo wa ‘ wo Ila Orun,
Ki bibo Re se ‘tunu wa.
Tu gbogbo isudede ka
M’ ese ati egbe kuro.

4. Wa omo ‘lekun dafidi,
‘Lekun orun y’ o si fun O
Tun ona orun se fun wa,
Jo se one osi fun wa.

5. Sunmo wa Oluwa ipa,
T’ o f’ ofin fun enia Re
Nigbani l’ or’ oke Sinai
‘Nu eru at’ agbara nla.

(Visited 689 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you