1. A NT’ ona t’ Oluwa war in:
A ngb’ agbelebu Re;
Gbogb’ egun t’o ngun wa l’ese
Ti gun l’ori saju.
2. Opo ‘gba l’ oju wa l’ ayo,
L’ o kun fun omije;
Orun nikan n’ ireti wa,
Ese si l’ eru wa.
3. A ngbon ‘darop ara wa nu,
A nmo si b’ a tin lo
B’ a ti nku s’ aiye on ese,
Be l’ orun wa nbere.
(Visited 258 times, 1 visits today)