YBH 107

OGABJO gan: l’ oke Olif

1. OGABJO gan: l’ oke Olif’
Awon irawo si ti wo;
Oganjo gan: nisisyi
Jesu nikan ngbadura l’ ogba.

2. Ogbanjo gan: l’ ais’ enikan,
Jesu nikan ba eru ja;
Omo-ehin t’ O fe papa
Ko nani ibanje Re.

3. Oganjo gan: f’ es’ lomi
En’ ikanu nsokun n’nu ‘ eje ;
Sibe en ‘t’ o wole l’ anu
Olorun ko je d’ ehin ko.

4. Oganju gan: lati papa
A nbg’ orun awon Angeli,
Orin titun t’ a ko gbo ri,
L’ o tu Olugbala l’ ara.

(Visited 210 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you