YBH 109

ENYIN ti nkoja

1. ENYIN ti nkoja
Ya sodo Jesu:
O s’ asan fun nyin bi, bi Jesu ba ku?

2. Alafia wa
Onigbowo wa:
Wa, wo b’ ibanuje kan ri bayi ri.

3. Oluwa n’jo na,
N’ ibinu Re gbe
Ese wa l’ Od’ -agutan, O ko won lo.

4. O ku, k’ O s’ etu
Nitor’ ese wa:
Baba se Omo Re n’ ise tori wa.

5. K’ a gb’ ore-ofe
Irapada mu:
Fun Enit’ o jiya t’ O ku n’ ipo wa.

6. Nigb’ aiye ba pin
Awa o ma bo
Ife totobi na, ti ki tan lailai.

(Visited 340 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you