YBH 114

AGBELEBU ni ere mi

1. AGBELEBU ni ere mi,
Nibe ni a rubo fun mi;
Nibe l’ a kan Oluwa mo
Nibe l’ Olugbala mi ku.

2. Kini o le fa okan Re
Lati te ‘ri gba iya mi?
Aim ohun na daju l’ o se
T’ okan mi tutu be si O.

3. Aifohun na ti mi
Niwaju Jesu mimo mi,
T’ O ta ‘je Re sile fun mi,
‘Tori o fe mi l’ afeju.

(Visited 543 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you