YBH 119

Oku! – Ore elese ku

1. Oku! – Ore elese ku
Omobirin Salem’ Sokun;
Okunkun bo oju orun,
Ile wariri lojiji.

2. Ife at’ ikanu l; eyi
Oluwa Ogo ku f’enia!
Sugbon ayo wo l’a ri yi –
Jesu t’ Oku tun ji dide!

3. Olorun ko boji sile,
O lo s’agbala Baba Re.
Ogun Angeli sin lo ‘le,
Nwon si fi ayo gba s’ oke,

4. Ma sokun mo, enyin mimo,
K’ e so giga ijoba Re;
Korin b’ O ti segun Esu,
T’ O si de iku lie won.

5. E wipe, “Oba wa titi,
Enit’ a bi lati gba la!”
E b’ iku pe, “Oro re da?”
Isa-oku, “‘Segun re da?”

(Visited 325 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you