1. ORUN, korin! Aiye, yo!
Angeli at’ enia,
E yi ka b’ O ti ndide,
E gbe ‘yin Jesu nyin ga.
2. A ti fo ejo l’ ori,
A segun ‘ku at’ Esu,
Labe Jesu t’ O goke,
A ti mu ‘gbekun l’ eru.
3. Ise at ija Re tan,
O lo sinu ayo Re,
O si mbe f’ awon Tire,
Nibi ite Baba Re.
(Visited 377 times, 1 visits today)