YBH 129

BELESE s’owo po

1. BELESE s’owo po,
Ti nwon nde s’Oluwa,
Dimo si Kristi Re,
Lati gan Oba na,
B’aiye nsata,
Pelu Esu,
Eke ni nwon,
Nwon nse lasan.

2. Olugbala joba
Lori oke sion,
Ase ti Oluwa
Gbe omo tire ro;
Lat’iboji
O ni k’Onde
K’ Osi goke,
K’o gba ni la.

3. F’eru sin Oluwa,
Si bowo f’ase Re,
F’ayo wa s’odo Re,
F’iwariri duro;
E kunle fun,
K’e teriba;
So t’ipa Re,
Ki omo na..

(Visited 1,149 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you