1. AFUN iho ayo mimu
S’ Olorun Oba nla!
K’ile gbogbo lo ahon won
K’o si korin ‘segun.
2. Jesu Oluwa goke
Eso orun yi ka,
Nwon ba goke bi O ti nlo,
Pelu iro fere.
3. B’ Angeli tin yin Oba won,
K’eda ko orin na;
Ki aiye korin ola Re;
O joba gbogb’aiye.
4. F’iberu nla wa iyin Re,
Fi oye ko orin na;
Ma fi ahon etan gan a
Nipa iyin ete.
(Visited 159 times, 1 visits today)