YBH 139

EYO Jesu joba

1. EYO Jesu joba
N’nu omo enia,
O da ara tubu,
O so won d’omnira:
K’esu koju s’Om’Olorun
Lai f’ota pe, ise Re nlo.

2. Ise ti ododo,
Oto Alafia,
Fun ‘rorun aiye wa,
Yio tan kakiri:
Keferi, ju, nwon o wole,
Nwon o je’je isin yiye.

3. Agbara l’owo Re,
Fun abo eni Re,
Si ase giga Re,
L’opo o kiyesi.
Orun ayo ri ise Re,
Ekusu rere gb’ofin Re.

4. Irugbin t’orun yi,
O fere d’igi nla;
Abukun ‘wukara,
Ko le saitan kiri,
Tit’Olorun Omo tun wa,
Ko le sailo, Amin! Amin!

(Visited 934 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you