YBH 141

EMI ‘bukun, bi afefe

1. EMI ‘bukun, bi afefe,
Ni nfe sibit’ o wu;
Awon, t’ iji re lu, bawo
L’ okan won ti yo to!

2. O ntun okan ‘fe ara mo,
O nte pa ese ba,
O ns’ okan okuta d’ eran,
A f’ ore Re sibe.

3. O ntan ‘fe Baba kakiri,
O nf’ eje we ni wo,
O nl’ ebi at’ eru wa lo,
A si mu wa wa ‘le.

4. Oluwa, tan ‘kan okun wa
F’ iye at’ ayo kun;
Ko s’ eniti o bori ‘pa Re,
To le ba ‘se Re je.

(Visited 145 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you