1. A WON eye n’ ife,
Kolokolo n’ iho, enia n’ ile:
Eda n’ ib’ isimi
Sugbon Jesu ko r’ ibi gborile.
2. Sibe O mu sinmi
Wa f’ awon elese on alare;
O f’ iye f’ elese,
O mu gbogbo ‘banuje wa kuro.
3. Mo ba ninu je ri,
Mo si ti bi Emi Re ninu ri,
Eni t’ a kan mo ‘gi
T’ a si fi ade egun de lori.
4. Ife Re ti ki sa
On na lofi alafia fun mi:
Eyi ti kio dekun,
Titi ngo d’ ajogun ijoba Re.
5. Bikos’ ore ofe,
Mo mo pee m,’ ki ba ti le ri
Oju Re didan ni
To ti sa fun roar nitori mi.
6. K’ eye wa ite won,
Kolokolo at’ enia ‘bubge won,
Oluwa w’ okan mi
Si f’ ori re le okan aya mi.
7. ‘Wo fe lati ma gbe
Okan ‘rele to kanu fun ese,
Wa ki O si simi
Nnu okan roar on ‘banuje yi.
(Visited 300 times, 1 visits today)