YBH 150

EMI, Olore ofe

1. EMI, Olore ofe,
Tan ‘mole Re s’ okan mi;
M’ eru ebi mi kuro;
F’ ife Re orun kun mi.

2. Je kin mo ‘dariji Re;
D’elese t’ eru npa ‘le;
To mi si Od’-agutan;
F’ eje Re owon we mi.

3. F’ alafia ‘ye fun mi;
Te igbala s’ okan mi;
Mi ara Re s’ aiya mi,
Ileri ‘simi lailai.

4. Ma je ki nya O titi;
Mu mi to ona toro;
F’ ayo orun k’ okan mi;
Se mi ni Tire laialai.

(Visited 498 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you