1. WA Emi Mimo, wa,
Pelu ipa t’ orun,
Si ran ninu anu Re nla
Sor’ okan okun wa.
2. Yo okan lile yi;
Te ‘fe agidi ba;
Bori gbogbo ifekufe,
K’ O si da mi l’ otun.
3. T’ emi l’ ere y’ o je,
Sugbon Tire n’ iyin;
‘Wo l’ emi o si fi gbogbo
Ojo mi t’ o ku sin.
(Visited 673 times, 1 visits today)