YBH 152

OLURAPADA wa, k’ On to

1. OLURAPADA wa, k’ On to
Dagbere ikehin,
O fi Olutunu fun mi,
Ti mba wa g be.

2. O wa ni awo adada,
O na iye bow a;
O tan ‘fe on alafia
S’ ori aiye.

3. O de, O mu ‘wa-rere wa,
Alejo Olore,
Gbat o ba r’ okan irele,
Lati ma gbe.

4. Tire l’ ohun jeje t’ a ngbo,
Ohun kelekele;
Ti nbaniwi, ti nl’ eru lo
Ti nso t’ orun.

5. Gbogbo iwa-rere t’ a nhun,
Gbogbo isegun wa;
Gbogbo ero iwa mimo
Tire ni won.

6. Emi Mimo Olutunu,
F’ iyonu be wa wo;
Jo s’ okan wa n’ ibugbe re
K ‘o ye fun O.

(Visited 267 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you