YBH 156

EMI anu, oto, ife

1. EMI anu, oto, ife,
Ran agbara Re t’ oke wa;
Mu iyanu ojo oni,
De opin akoko gbogbo.

2. Ki gbogbo orile-ede,
Ko orin ogo Olorun,
Ki a si ko gbogbo aiye,
N’ ise Olurapada wa.

3. Olutunu at’ Amona,
Joba ijo enia Re,
K’araiye mo ibukun Re,
Emi anu, oto, ife.

(Visited 333 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you