YBH 157

OGO fun Olorun Baba

1. OGO fun Olorun Baba,
Ogo f’ Olorun Omo,
Ogo fun Olorun Emi,
Jehofa, Metalokan;
Ogo, ogo.
B’ aiyeraiye ti nkoja.

2. Ogo fun Enit’ o few a,
T’ o we abawon wa nu;
Ogo fun Enit’ o raw a,
T’ o mu wa ba Onj’ oba;
Ogo, ogo,
Fun Od’-agutan t’ a pa.

2. “Ogo, ‘bukun, iyin lailai!”
L’ awon ogun orun nko;
“Ola, oro, ipa, ‘joba!”
L’ awon eda fi nyin I,
Ogo, ogo,
Fun Oba awon oba.

(Visited 1,679 times, 11 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you