YBH 159

F’ ORUK’ Olorun loke

1. F’ ORUK’ Olorun loke,
T’ O l’ agbara at’ ola,
Olorun ibi gbogbo,
N’ iyin ati ogo wa.

2. F’ oruko Krist’ Oluwa,
Om’ Olorun ti a bi,
Krist’ t’ O da ohun gbogbo,
Ni k’ a san ‘yin ailopin.

3. F’ Olorun Emi Mimo,
Ni k’ iyin pipe w alai,
Pelu Baba at’ Omo,
Okan l’ oruko l’ ogo.

4. Orin t’ a ti ko koja,
T’ ao si ma ko lai l’ eyi;
Ki awon iran ti mbo
Dapo korin didun na.

(Visited 169 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you