YBH 164

ASAN n’ ireti t’ enia ko

1. ASAN n’ ireti t’ enia ko
Le ori ise won:
A bi won pel’ okan eri,
Ebi si n’ iwa won.

2. Ki ju, ati ki keferi
Teriba n’ idake;
K’ enia jewo ebi won,
Niwaju Olorun.

3. Lasan l’ a ntoro ‘dalare
Lowo ofin pipe;
Ilaju at’ idalebi,
Ni ofin le mu wa.

4. Jesu, ore Re ti dun to,
T’ a ba gbekele O,
‘Gbagbo wa ri ododo gbe,
T’ o je k’ elese pe.

(Visited 192 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you