YBH 165

GBAT’ emi re ba fo lo

1. GBAT’ emi re ba fo lo,
T’ iku ba siji bo o;
‘Gbati sa re ba pari,
Elese n’ bo l’ o yo si?

2. ‘Gbati aiye ba koja,
T’ ojo ‘dajo sunmole,
Ti ipe nla nib a dun;
Wi, ni ibo l’ o yo si?

3. Gbat’ Onidajo ba de,
Enit’ a wo l’ agbara,
T’ elese ba nwariri:
Nibo li o yoju si?

4. Kini y’o re o l’ ekun,
Nigba ipinju ba de?
T’ eni ‘re d’ ade ayo,
Elese, n’bo l’ao ri o?

5. Niwon t’ Emi sunmo wa,
Sa to Olugbala lo,
Emi re y’o ri isimi,
O yoju s’ orun rere.

(Visited 256 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you