1. LONI ni Jesu pe!
Asako wa;
A! okan okunkun
Ma kiri mo.
2. Loni ni Jesu pe,
Tetilele:
Ni ile owo yi,
Wole, Jesu.
3. Loni ni Jesu pe!
Sa asala:
Iji igbesan mbo,
Iparun mbo.
4. Loni ni Emi pe!
Jowo ‘ra re;
Ma mu k’ o binu lo,
Sa anu ni.
(Visited 895 times, 1 visits today)