1. BABA wa ti o mbe l’ orun,
Owo l’ oruko Re,
‘Joba Re de, ife Re ni
K’ a se bi ti orun.
2. Fun wa l’ onje ojo loni,
Dari ese wa ji,
Gege bi a ti ndariji
Awon ti o se wa.
3. Ma sin wa sinu idanwo,
Yo wa ninu ewu,
Nitori ‘joba ni Tire,
At’ ogo titi lai.
(Visited 1,164 times, 1 visits today)