1. WA rohin Re yika
K’o si korin ogo;
Alagbara ni Oluwa
Oba gbogbo aiye.
2. Wa, wole n’ ite Re,
Wa teriba fun U;
Ise owo Re l’ awa se
Oro Re l’ o da wa.
3. Loni gbo ohun Re,
Mase fa ‘binu Re,
Wa, bi awon ayanfe,
Jewo Olorun re.
(Visited 396 times, 1 visits today)