YBH 170

OKAN apata tuba

1. OKAN apata tuba,
K’ eje Jesu mu o ro:
Wo ara Re ti a gun,
Wo bi eje ti bo O,
Elese, kil’ o se yi?
O kan mo agbelebu.

2. Loto, ese re lo se,
L’o kan ‘so t’o mumo ‘gi,
L’o fie gun de l’ ade,
L’o fie oko s’ egbe Re;
O s’ okan Re d’ etutu,
Ni kiku fun elese.

3. Eje Re y’o j’ asan bi?
O ha le d’ oju iku?
Tun si oju ogbe Re?
Se agbalebu otun?
Beko, ngo ko ese mi,
Tuba, iwo, okan mi.

(Visited 187 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you