YBH 174

OLUWA mo gb’ ohun Re

1. OLUWA mo gb’ ohun Re,
Ti npe mi wa ‘do Re,
Fun ‘wenumo n’nu eje Re
T’o san ni Kalfari.
Mo Mbo Oluwa,
Mo Mbo s’ odo Re
We mi ninu eje Re
T’ o nsan ni Kalfari.

2. Bi mo nbo nnu ailera
‘Ranlowo Re daju
‘Wo mu ailera mi kuro
Emi si di mimo.

3. Jesu li o pe mi
Si ‘gbagbo on ife,
Si ‘reti ati eje Re
T’ o nsan ni Kalfari.

4. Jesu ni o nsise
Ibukun ninu mi
Nipa opo ore ofe
N’ ibi t’ ese njoba.

5. O si fi eleri
Si okan otito
Pe ileri gbogbo yo se
Bi a be n’ igbagbo.

6. A eje etutu
A! ore ‘rapada
A ebun krist’ Oluwa wa,
L’ okun ododo wa,

(Visited 1,487 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you