YBH 176

ENIT’ o ba gbo, kigbe iro na

1. ENIT’ o ba gbo, kigbe iro na,
Ran ihinrere na si gbogbo aiye
Tan ihin na ka ‘bi gbogbo t’ enia wa,
“Enit’ o ba fe le wa?
“Enit’ o ba fe, Enit’ o ba fe?”
Ran akede s’ oke ati petele;
Baba on ife l’ o np’ asako wa ‘le
“Enit’ o ba fe le wa?”

2. Enit’ o ba nbo ko ye k’ o duro,
Ilekun si nisisiyi, wa wole;
Jesu nikan li Ona, Iye, Oto,
“Enit’ o ba fe le wa.

3. “Enit’ o ba fe,” a pa ‘leri na mo;
“Enit’ o ba fe,” yio duro titi lai
“Enit’ o ba fe,” iye ni titi lai;
“Enit’ o ba fe le wa.

(Visited 362 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you