YBH 179

EBI ese npa mi l’ eru

1. EBI ese npa mi l’ eru,
O te ori mi ba,
Oluwa fi okan eran
Paro t’ okuta mi.

2. Mo de, eru ese npa mi,
Iku mba mi l’ eru;
F’ eje Re te ‘dariji mi,
Si le eru mi lo.

3. Okan mi ko le r’ simi
Titi ngo fi kigbe
Li abe agbelebu Re,
Pe, “Jesu ku fun mi.”

4. Fun mi lati ni igbagbo,
Ati iriri yi,
Titi iwa ogbo yio lo,
T’ okan mi yio d’ orun.

(Visited 203 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you