1. OLUWA, Ob’ Alase,
A wole ni ese Re;
Gbo igbe itara wa,
Bi O ba r’ oju, ao ku.
2. O to, bi oko iku
Ba gun, okan ebi wa,
O to, bi ategun Re
F’ iku ailopin pa ni.
3. Jesu gba okan ‘ku wa,
Mu emi are soji;
A nra ninu ekuru,
Jesu mase je k’ a ku.
(Visited 183 times, 1 visits today)