1. WO Oluwa oke,
Ati abe ‘sanma;
Mo do bale li ese Re,
Mo nke fun anu Re.
2. Dari ‘were ji mi,
Ese ti mo ti da;
So fun okan ofo, po ye
Nip’ Omo bibi Re.
3. Ebi, bi eru nla
Wa l’ori okan mi,
Iwo ni mo roe dun fun,
‘Wo ni mo sokun ba.
4. Inira ti mo ri,
‘Wo lo le mu kuro;
Oluwa f’idariji han,
At’opo ife Re.
5. Oju anu Re kan
Ko f’aiya mi bale,
Je kin mo p’a dariji mi,
Ngo d’alabukunfun.
(Visited 239 times, 1 visits today)