1. IBU ife! O le je
Pe a p’anu mo fun mi;
Olorun mi ha le da
‘Binu ro fun elese?
2. Mo ti mb anu ja tip e!
Mo ti nbi n’inu tip e!
Mo di ‘ti si ife Re,
Mo f’op’ese bi ninu.
3. Jesu dahun lat’ oke,
O ki ha se kik’ife?
Mo wole li ese Re,
O k’yo ha m’ oju kuro?
4. Mu mi te si ironu,
Ki nle sokun f’ese mi,
Ki nkedun fun iwa mi,
Ki ngbagbo, kin ma se mo.
(Visited 319 times, 1 visits today)