1. OLUGBALA, lie se Re
L’olote kan wole ,
O si f’igboiya gb’oju wo
‘Te anu Re loke.
2. Bi omije aro ba to
San ‘gbese ti mo je,
Ekun ‘ba ma san li aida
L’oju mi mejeji.
3. Ki s’ebo yi ni mo mu wa
Fun ‘mukuro ese;
Bikose ekun t’O ti sun
At’eje t’O ta ‘le.
4. ‘Tori iya Re ni mo be,
Dari ese ji mi:
Ododo Re ki y’o kop e
Ki elese k’o la.
(Visited 116 times, 1 visits today)