YBH 184

MO ti mb’ese rin ti pe

1. MO ti mb’ese rin ti pe,
Pin wa n’iya, Oluwa,
Ore’parun ni tire,
Gba mi Jesu, mo segbe.

2. ko s’ anfani ti mo ri
L’ ara ati l’ okan mi,
Gbogbo re l’ o dibaje,
Jesu gba mi, mo segbe.

3. Mo r’ iye nin’ oro Re,
Ibagbe Re si wu mi,
Ese di mi mu sinsin
Gba mi Jesu, jo gba mi.

4. O ha dake ki nsegbe,
Nitori ailera m?
Oha jowo mi f’ ese?
K’ a ma ri, Jesu gba mi.

5. Iwo t’ o r’ ode,
Iyanju mi han si O,
O mo bi mo ti nja to,
O r’ omije ‘koko mi.

6. Ese fie won de mi,
Da mi, Oluwa da mi,
Iwo ni ngo sin titi,
Jesu Olugbala mi.

(Visited 442 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you