1. ESE mi po bi irawo,
B’ iyanrin let’ okun;
Sugbon iyonu Olorun,
O papoju be lo.
2. Manase, Paul on Magdalen,
Iwo dariji won;
Mo ti ka, mo si gbagbo pe
O ti dariji mi.
(Visited 231 times, 1 visits today)
1. ESE mi po bi irawo,
B’ iyanrin let’ okun;
Sugbon iyonu Olorun,
O papoju be lo.
2. Manase, Paul on Magdalen,
Iwo dariji won;
Mo ti ka, mo si gbagbo pe
O ti dariji mi.
We promise not to spam you