YBH 192

JESU nfe gba elese

1. JESU nfe gba elese,,
Kede re fun gbogb’ eda;
T’o yapa ona ‘run ‘le,
At’ awon ti njafara.
Ko o l’ orin, ko sit un ko,
Kristi ngba gbogb’ elese;
Je k’ ihin na daju pe,
Kristi ngba gbogb’ elese

2. Wa, y’O fun o n’ isimi,
Gba A gbo, ore re ni;
Y’O gb’ elese t’o buru,
Kristi ngba gbogb’ elese.

3. Okan mi ko l’ ebi mo,
Mo mo niwaju ofin;
Enit’ o ti we mi mo,
Ti san gbogbo gbese mi

4. Kristi ngba gbogb’elese,
An’emi t’o d’ese ju;
T’a we mo patapata,
Y’o ba wo Joba orun

(Visited 4,029 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you