1. BI o ti ri laisi ami
Ife, ayo, tab’ ore kan,
T’ o ye fun ibugbe orun,
Elebi, ma bow a.
2. Mo ru ese re lor’ igi;
Mo gba ore t’ o to si o,
K’ idariji le je ofe,
Eleri, ma bow a.
3. F’ ese re ti agbelebu;
Ka gbogbo oro re s’ ofo;
Ore Mi san ofo gbogbo,
Alaini ma bow a.
4. Mu ifoiya re wa nihin ,
Okan ‘rora at’ ekun re;
Ohun anu l’ o ndun si o,
Eni eru, ma bo.
5. Emi at’ Oko, ‘yawo npe,
Awon mimo nf’ ayo pe, “Wa!”
Eniti ongbe ngbe le wa,
Jesu wipe k’ o wa.
(Visited 328 times, 1 visits today)