YBH 202

ALAFIA w’ okan, t’ ohun re

1. ALAFIA w’ okan, t’ ohun re
Ko apata l’ ohun aro:
Dekun ejo wi, pa ‘nu mo,
Ki ekun ye san l’ oju re;
Wo, a ri ogun t’ o dara
Lati tu o, ko tan ‘gbe re.

2. Wa, l’ ofe, iwo ti ns’ ise,
So eru re kale nihin;
Ri abo at’ isimi n’bi,
Gbekel’ anu Olorun re:
Olorun re l’ Olugbala!
Feran Re, yin titi aiye.

(Visited 204 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you