1. WA sodo Jesu, mase duro,
N’ oro Re l’ O ti f’ ona han wa,
O duro li arin wa loni,
O nwi jeje pe, “Wa.”
Refrain
Ipade wa yio je ayo,
Gb’ okan wa ba bo lowo ese,
Ao si wa pelu Re, Jesu,
Ni ile wa lailai.
2. “Jek’ omode wa,” a! gb’ ohun Re!
Jek’ okan gbogbo fo fun ayo;
Ki a si yan A l’ ayanfe wa;
Ma duro, sugbon wa.
Refrain
Ipade wa yio je ayo,
Gb’ okan wa ba bo lowo ese,
Ao si wa pelu Re, Jesu,
Ni ile wa lailai.
3. Tun ro, O wa pelu wa loni,
F’ eti s’ ofin Re, k’ o si gboran,
Gbo b’ ohun Re ti nwi pele pe,
“Wa, omo Mi, e wa!”.
Refrain
Ipade wa yio je ayo,
Gb’ okan wa ba bo lowo ese,
Ao si wa pelu Re, Jesu,
Ni ile wa lailai.
(Visited 11,431 times, 2 visits today)