YBH 214

PADA asako s’ ile re

1. PADA asako s’ ile re,
Baba re l’ O npe o;
Ma se alarinkiri mo,
N’nu ese at’ osi.
Pada, pada, pada.

2. Pada asako s’ ile re,
Jesu l’ O sa npe o;
Emi pelu ijo si npe,
Yara sa asala.
Pada, pada, pada.

3. Pada asako s’ ile re,
Were ni b’ o ba pe,
Ko si ‘dariji n’ iboji,
Ojo anu kuru
Pada, pada, pada.

(Visited 889 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you